× About Services Clients Contact

Abiamo

$600
Oyo
Add to Wishlist Call Seller 08079833768 Send Message Chat On Whatsapp

Description

Abiku da Titilayo laamu gan-an. Oju re ri mabo lodo awon adahunse ati awon bab yemiwo. Durogbaye nikan soso lo duro ninu omo mokanla ti o bi. Ohun ti oju Titilayo ri ki Durogbaye naa to duro ko kere. Bi Durogbaye ti pe omo odun mewaa ni baba re ti jade laye.

Titilayo nikan lo n da bukata omo re gbe lati igba naa. Titilayo gira to Durogbaye ti o fi kekoo gboye ni Yunifasiti ni. Se Durogbaye duro sanjo fun iya re? Nje Titilayo naa jeun omo ki o to re ibi agba re?

Photos

Other Details

Price $600
Type Paperbook
Book ISBN 9783527246-6
Author(s) Biola Owoade
Book Publisher Accessible Publishers Ltd.

Reviews (0)

(Overall 0 Out of 5)
No Review Found

Write a Review