× About Services Clients Contact

Bisola Lo Sile Iwosan

$900
Oyo
Add to Wishlist Call Seller 08079833768 Send Message Chat On Whatsapp

Description

Bisola lo sile iwosan je iwe aladun ti o da lori odomode binrin ti oruko re n je Bisola, ti o feran oogun lilo ju abere lo nigba ti o n saisan. Iwe akoni logbon yii to ni sona lati lo si ile-iwosan lati gba itoju loore-koore, ki a si jina si lilo oogun laisi itoni onisegun.

O tun toka si awon igbese ati ilana ti alaisan gbodo tele ni ile-iwosan. Awon aoran re joju ni gbese. O si dun pupo lati ka nitori ewa ede Yoruba ni kinun la fi ko o.

Photos

Other Details

Price $900
Type Paperbook
Book ISBN 978-978-85532-1-2
Author(s) Bolaji Ladipo
Book Publisher Accessible Publishers Ltd.

Reviews (0)

(Overall 0 Out of 5)
No Review Found

Write a Review