× About Services Clients Contact

Ekute Ile wa

$900
Oyo
Add to Wishlist Call Seller 08079833768 Send Message Chat On Whatsapp

Description

Ekute Ile Wa da lori awon ose ati ijanba ti ekute nse ninu ile. Iwe yii lo onati o pani lerin-in jojo lati toka si idaamu ati adanu lorisiirisi ti ekute gbe ba awujo omo eniyan. Paapaa julo, lai fi iwe pe, ninu ile onile, ti odomode kan ati awon obi re.

Ekute ba awon ohun ini won je gidigidi, titi de idi ounje won. Eyi ti ko ba tunh le e je, a fi se awadanu. Sugbon, se bi omode ba ni aso bi agba, se o le ni akisa bi agba ni? E so ki ngbo. Awon obi odomode yii fi ogbon agba ti o le ko awon omode ni imo ati oye reyin gbogbo ekute inu ile patapata.

Photos

Other Details

Price $900
Type Paperbook
Book ISBN 978-978-85532-0-5
Author(s) Bolaji Ladipo
Book Publisher Accessible Publishers Ltd.

Reviews (0)

(Overall 0 Out of 5)
No Review Found

Write a Review