Description
Akekoo ti muse-muse re da muse ni Monisola. Nse ni oga ile-eko won maa n fi i yangan nitori pe o ti gba opolopo amieye fun ile-eko won. Monisola gbo faari pupo.
Ape-marindoti ni laarin awon akekoo akegbe re. Ki i wo aso ile-eko kan ni ojo meji laifo. Ohun ti oju re ri ni ile-iwosan nigba ti o saisan lo se okunfa ipinnu re lati di onisegun oyinbo
Photos
Other Details
Price | $600 |
Type | Paperbook |
Book ISBN | 978802413-0 |
Author(s) | Biola Owoade |
Book Publisher | Accessible Publishers Ltd. |
Reviews (0)
(Overall 0 Out of 5)
No Review Found