Description
Itan inu iwe ORI OKERE KOKO LAWO da lori akitiyan awon obi Adigun lati ri pe o nise lowo nitori ojo iwaju re. O ko o ni oun o nise se. Ogboju logun. O gbagbe pe eni ti o ba gboju logun fira re fosi ta. Leyin iku awon obi re, atije, atimu dogun si i lorun. Ibi ti o ti n lakaka lati wa ona abayo si isoro ti o doju ko o, o wegbe kegbe. Owo te ouon ati awon omo egbe re. Eda ti o ba fori gbe ile agbon, o di dandan kagbon o ta a. Ni kukuru ede, Adigun rugi oyin, o si ge ika abamo je
Photos
Other Details
Price | $600 |
Type | Paperbook |
Book ISBN | 978851685-8 |
Author(s) | Tubosun Afolarin |
Book Publisher | Accessible Publishers Ltd. |
Reviews (0)
(Overall 0 Out of 5)
No Review Found