× About Services Clients Contact

Tisa Isiro

$600
Oyo
Add to Wishlist Call Seller 08079833768 Send Message Chat On Whatsapp

Description

Ogbeni Morayo kan, ile-eko Mogba kan ni. Ko fi aye gba gberee rara. O mo bi a ti n fi egba sin ileke si idi omo alaigboran. O le lu akekoo daku nitori isiro. Se otito ni pe isiro lo le ju ninu gbogbo ise? Se bi awon akekoo ile eko Mogba se lero pe isiro le to, se bee lori?

Se ogbeni Morayo funrare mo isiro ti o fe lu awon omo olomo pa si yii? Itu wo ni oluko isiro fi awon akeoo wonyi pa? Bira wo ni awon akekoo naa fi oluko isiro yii da? Kin ni o gbeyin oro isiro ati awon akekoo ile-eko Mogba pelu tisa isiro won? A fi ki e farabale ka itan yii ni akagbadun ki e le mo bi isu se ku ati bi obe se be e.

Photos

Other Details

Price $600
Type Paperbook
Book ISBN 978501922-5
Author(s) Niyi Mofeyintola
Book Publisher Accessible Publishers Ltd.

Reviews (0)

(Overall 0 Out of 5)
No Review Found

Write a Review